- Sisopapọ ijẹrii mejeeji, nitori naa ọkan ninu mejeeji o lee ni alaafia ayaafi pẹlu ikeji; fun idi eyi ni wọn fi ṣe mejeeji ni origun kan.
- Ijẹrii mejeeji ni ipilẹ ẹsin, nitori naa wọn o nii tẹwọ gba ọrọ kan abi iṣẹ kan ayaafi pẹlu mejeeji.
Àlàyé
Hadeeth benefits